BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìdílé
Ọdún méjìdínlógún ni mo fi wojú Ọlọ́run fọ́mọ kí n tó bí ìbejì - Ricardo Agbor
11 Agẹmo 2026
"Abuja ni ọmọ mi ní òun ti ń ṣiṣẹ́, kìí ṣe oníjọ̀ngbọ̀n, àhésọ̀ ọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ kò yé mi tí ọlọ́pàá ṣe ba irin ara ògiri àti ìlẹ̀kùn ilé jẹ́ láti fi tipá wọlé"
8 Agẹmo 2026
Kò tọ́ kí àwọn kan máa fi òbítíbitì owó kun àtíkè lọ́jọ́ ìgbéyàwó nígbà tí ebi ń pa àwọn míì - Emir Zazzau
4 Agẹmo 2026
Mọ̀lẹ́bí Kola Oyewo kéde bí ètò ìsìnkú rẹ̀ yóò ṣe wáyé
4 Agẹmo 2026
'Àwọn dókítà yọ kíndìnrín mi lásìkò iṣẹ́ abẹ ìbímọ'
3 Agẹmo 2026
3:45
Fídíò,
N kò le fẹ́ ọkùnrin tó lówó, n kò sì le bá ọkùnrin jìyà tàbí ṣe ìyàwó kejì àbí ìkẹta - Eyiyemi Afolayan
, Duration 3,45
24 Òkùdu 2026
9:37
Fídíò,
"Búrẹ́dì ni ọkọ mi lọ rà fún àkọ́bí wa, tí wọ́n fi ṣá a pa ní ọ̀sẹ̀ kan lẹ́yìn ìkómọ ọmọ wa kejì"
, Duration 9,37
23 Òkùdu 2026
Father's Day: Kí ni pàtàkì àyájọ́ ọjọ́ bàbá àti ìtàn tó rọ̀ mọ?
21 Òkùdu 2026
1:46
Fídíò,
Líla ọwọ́ sí àwọn ẹbí àti ọ̀rẹ́ rẹ lè jẹ́ kí ẹ̀mí ré gùn - Ìwádìí
, Duration 1,46
18 Òkùdu 2026
Kí ló dé tí ẹnu ń kun Bàbá Ijesha lẹ́yìn tó kéde ọmọ tuntun?
16 Òkùdu 2026
1:48
Fídíò,
'Fóònù àti tẹlifíṣàn àwòjù le è ṣe àkóbá fún ọpọlọ ọmọ rẹ'
, Duration 1,48
21 Èbibi 2026
"Ọlọrun ti gba ọkọ mi!" Niniola, gbajúmọ olórin tàkasúfèé kéde ikú ọkọ rẹ̀
20 Èbibi 2026
Lateef Adedimeji kéde orúkọ àwọn ìbẹ́ta rẹ àti ọjọ́ tí wẹ̀jẹwẹ̀mu ìdúpẹ́ yóò wáyé
9 Èbibi 2026
Ọkùnrin tí wọ́n sinòkú rẹ padà wọ ìlú, ariwo sọ
5 Èbibi 2026
Èèyàn 300 ṣe ìgbéyàwó ní Gaza láàárín ogun tó ń wáyé níbẹ̀
26 Ìgbé 2026
Bàbá kan yìnbọn pa ọmọ rẹ̀ méje àti ọmọ ọlọ́mọ kan
21 Ìgbé 2026
1:46
Fídíò,
'Ó kìí ṣe ọmọ ìyá mi mọ́' : Wo bí ogun tó ń wáyé ní Iran ṣe ń tú ẹbí ká
, Duration 1,46
6 Ìgbé 2026
"Ń ṣe ni inú mi máa ń bàjẹ́, tí mo bá rántí pé ọmọ ìyá mi ló da ásíìdì sí èmi àti ìyàwó mi lára, tí àwọ̀ ara mi fi bàjẹ́"
4 Ìgbé 2026
1:27
Fídíò,
Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé
, Duration 1,27
12 Ẹrẹ̀nà 2026
3:03
Fídíò,
Wo tọkọtaya tó ń gba àwẹ̀ Lent àti Ramadan papọ̀
, Duration 3,03
9 Ẹrẹ̀nà 2026
Èèmọ̀ ńlá ! Suleiman pa ẹ̀gbọ́n rẹ̀ nílùú Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí, Ó ní torípé ó yìnbọn fún òun lójú àlá
4 Ẹrẹ̀nà 2026
Àjọ NSCDC kẹ́dùn ikú òṣìṣẹ́ rẹ̀ tí ọkọ̀ tẹ̀ pa l'Abuja
1 Ẹrẹ̀nà 2026
Taiwo Adegbodu, olórin ẹ̀mí ẹgbẹ́ Adegbodu Twins jáde láyé
1 Ẹrẹ̀nà 2026
Ṣé lóòótọ́ ni pé fífẹ́ ju ìyàwó kan lọ máa ń mú ẹ̀mí ọkùnrin gùn si?
19 Èrèlè 2026
Page
1
nínú
33
1
2
3
4
5
6
7
33
Tókàn
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology