Ní àtijọ́, ìyàwó kìí pe àbúrò ọkọ rẹ̀ lórúkọ̀, báwo lọ̀rọ̀ ṣe rílóde òní? Amina Eleha sọ̀rọ̀ lórí àwọn òṣèré àti ríran ara wọn lọ́wọ́

Àkọlé fídíò, Amina Eleha, nibo laye kọju si?
Ní àtijọ́, ìyàwó kìí pe àbúrò ọkọ rẹ̀ lórúkọ̀, báwo lọ̀rọ̀ ṣe rílóde òní? Amina Eleha sọ̀rọ̀ lórí àwọn òṣèré àti ríran ara wọn lọ́wọ́
Published

Ṣé ìyàwó ṣì ń pé àbúrò ọkọ́ tí wọ́n bá níléNinu aṣa ilẹ Yoruba, nigba kan bi obinrin ba fẹ ọkọ, o ni lati bu ọwọ to tọ fun awọn aburo ọkọ to ba ba nile. Amọṣa lode oni ọrọ ko fi bẹẹ ri bayii mọ.

Lori eto nibolaye kọjusi ọtẹ yii, a gbe eyi yẹwo, ero awọn eniyan to ba wa sọrọ si le kenka.

Bakan naa ni gbajumọ oṣere, Amina Ẹlẹha naa sọrọ lori ẹsun ti wọn fi n kan awọ̀n oṣere tiata pe wọn kii n ran ara wọn lọwọ.