Àwọn ìgbésẹ̀ tó yẹ fún ọ láti gbé lọ́jọ́ ìdìbò
Àwọn ìgbésẹ̀ tó yẹ fún ọ láti gbé lọ́jọ́ ìdìbò
Published
Ajọ eleto idibo, INEC, ti sọ igbesẹ ti awọn oludibo gbọdọ gbe ki wọn to le dibo lọjọ idibo.
Oṣiṣẹ ajọ INEC to ba BBC Yoruba sọrọ lori eto laa han mi ti ọsẹ yii ṣalaye lẹsẹlẹsẹ awọn igbesẹ naa.
Gẹgẹ bo ṣe sọ, ṣaaju ọjọ idibo ni INEC ti ni orukọ awọn oludibo lọwọ, orukọ na si ni wọn yoo lẹ si ara ogiri nibudo idibo.
Ninu alaye rẹ lo ti sọ ohun ti awọn olugbọdọ ṣe lẹsẹṣe lẹyin ti wọn ba ri orukọ wọn tan titi ti wọn yoo fi tẹ ika lati dibo.
Gbogbo ohun ti obinrin naa sọ wa ninu fidio oke yii.



