BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ẹsin igbagbọ
Arafat Day: Wo ohun márùn-ún tí ayájọ́ òní fi lọ́lá jùlọ nínú Islam
26 Èbibi 2026
"Ìṣọ́ òru ní ṣọ́ọ́sì àti mọ́ṣáláṣí dópin, ìsìn kò gbọdọ̀ ju wákàtí méjì lọ, káwọn ṣọ́ọ̀ṣì tó wà ní ìgbéríkò sì kó wá sáàrin ìlú torí ìkọlù agbébọn"
25 Èbibi 2026
"Òfin tó mú Eleha ló mú eléégún, ẹ fààyè gbàwọn ẹlẹ́sìn àbáláyé náà láti máa wọ aṣọ ìbílẹ̀ lọ ilé ẹ̀kọ́ ISI n'Ibadan"
21 Èbibi 2026
Ilé ẹjọ́ ju pásítọ̀ sí ẹ̀wọ̀n gbére fún bíbá ọmọdé mẹ́ta lò pọ̀, ó tún ṣẹ́ oyún fún wọn
15 Èbibi 2026
5:59
Fídíò,
Ṣọ́ọ̀ṣì kan rèé tí wọn kií lanu sọ̀rọ̀, ọwọ́ lásán làwọn akọrin, oníwàásù àti olùjọ́sìn fi ń júwe
, Duration 5,59
12 Èbibi 2026
Ìdí rèé tí mo fi pinnu láti má lọ sí ṣọ́ọ̀ṣì mọ́ - Funke Akindele
4 Èbibi 2026
Àbọ̀ ìwádìí EFCC rèé lórí Pasitọ Jerry Eze tó ní òjò Dọ́là àti Pọ́ùn ń rọ̀ sínú àkáǹtì rẹ̀ fún oṣù mẹ́fà
1 Èbibi 2026
Ìṣọ́ òru di ibùdó ẹ̀jẹ̀ níjọ CAC Eda Oniyo l‘Ekiti, agbébọn pa pásítọ̀, jí ọ̀pọ̀ ọmọ ìjọ gbé lọ
29 Ìgbé 2026
"Ẹ̀yin ọ̀dọ́ tí ẹ̀ ń kún pé bí Toun Soetan ṣe ń kọrin ń di yín lọ́wọ́ láti dárà nínú ìjọ, ó ti lọ, ẹ wá dárà yín ká rí i"
17 Ìgbé 2026
2:44
Fídíò,
Ilẹ̀ Cameroun fi tijó-tìlù pàdé Pope Leo XIV
, Duration 2,44
16 Ìgbé 2026
Àbọ̀ ìwádìí BBC lórí ikú ìyàwó Wòlíì olùdásílẹ̀ ìjọ tó ń ṣe ọ̀pọ̀ èèyàn ní kàyééfì
15 Ìgbé 2026
Eré Àjíǹde di wàhálà! Akẹ́kọ̀ọ́ dèrò ilé ìwòsàn lẹ́yìn tí wọ́n lú ú bí bàrà lásìkò tó ṣe Jesu nínú eré Ajinde
6 Ìgbé 2026
Ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì ṣo ohun tó pa Jesu
5 Ìgbé 2026
Ilé ẹjọ́ gbẹ́sẹ̀ lé ilẹ̀, ilé ìtura, àtàwọn dúkìá míì tí wọ́n ní pásítọ̀ fi ọ̀nà èrú kó jọ
4 Ìgbé 2026
Kí ló kan Ẹyin àti Ehoro nínú ìtàn àti ayẹyẹ ọdún Àjíǹde Jesu?
4 Ìgbé 2026
Kí ló jẹ́ kí wọ́n máa pe ọjọ́ tí wọ́n kan Jésù mọ́ igi agbelebu ní ọjọ́ Ẹtì rere?
3 Ìgbé 2026
Wo ohun tó mú àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi 'Palm Sunday' yàtọ̀
29 Ẹrẹ̀nà 2026
Ìdí rèé táwọn Ẹlẹ́rìí Jehofa fi lè gba ẹ̀jẹ̀ ará wọn pamọ́ báyìí láti lò fún ìtọ́jú tó bá nílò kí wọ́n gbẹ̀jẹ̀
22 Ẹrẹ̀nà 2026
Mi ò ní í ṣe aláìní láyé mi, èmi àti Ọlọ́run nìkan la ní ọrọ̀ jù - Pásítọ̀ Chris Oyakhilome
21 Ẹrẹ̀nà 2026
3:03
Fídíò,
Wo tọkọtaya tó ń gba àwẹ̀ Lent àti Ramadan papọ̀
, Duration 3,03
9 Ẹrẹ̀nà 2026
Ìdí tí èmi àti Tinubu kò fi gbéná wojú ara wa rí láti ìgbà tí a ti ṣègbéyàwó fún bíi ogójì ọdún - Oluremi Tinubu
7 Ẹrẹ̀nà 2026
Nǹkan yan nínú ìjọ Anglican, àwọn àlùfáà tó pe ara wọn ní Gafcon lábẹ́ ìjọ náà yan bísọ́ọ̀bù àgbà tuntun tako bíṣọ́ọ̀bù Canterbury
5 Ẹrẹ̀nà 2026
Ash Wednesday 2026: Wo ìtumọ̀ àyájọ́ 'Ash Wednesday' tó wáyé lónìí àti pàtàkì rẹ̀ fún àwọn krìstíẹ́nì?
18 Èrèlè 2026
Gbogbo àwọn olùjọ́sìn táwọn agbébọn jí gbé ní Kaduna gba ìtúsílẹ̀
5 Èrèlè 2026
Page
1
nínú
24
1
2
3
4
5
6
7
24
Tókàn
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology