Àwọn ohun tí mo là kọjá ló tọ́ mi sọ́nà tí mò ń tọ̀ báyìí - Dieko, ọmọ Kunle Afolayan sọ̀rọ̀

Àkọlé fídíò, Àwọn ohun tí mo là kọjá ló tọ́ mi sọ́nà tí mò ń tọ̀ báyìí - Dieko, ọmọ Kunle Afolayan sọ̀rọ̀
Àwọn ohun tí mo là kọjá ló tọ́ mi sọ́nà tí mò ń tọ̀ báyìí - Dieko, ọmọ Kunle Afolayan sọ̀rọ̀
Published

Dieko Afolayan sọ fun BBC pe oun fẹran lati maa kọrin, lati maa se ounjẹ ati lati maa wọ aṣọ, paapaa lati maa ṣe awọn nnkan ti yoo mu inu oun dun.

O ni ẹnikẹni ko le di oun lọwọ lati ṣe nnkan ti yoo mu inu oun dun, ti yoo si jẹ koun pẹ nile aye.

"Mo nifẹ si ki n maa kọrin, se ounjẹ, ki n maa wọ aṣọ, ki n maa ṣe irun, ki n maa ba awọn eeyan sọrọ. Mo fẹran ki n maa ran awọn eeyan lọwọ," Dieko sọ fun BBC bẹẹ.

O tẹsiwaju pe, "Mo nifẹ lati maa da wa, to maa fun im lanfaani alti ronu daadaa, awọn nnkan ti mo nifẹ si nipa ara mi niyẹn."