Irinṣẹ́ òǹkà ọdún ti wà láti ka iye ọdún tó leè lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé, iye ọdún tó ṣeé ṣe kí gbogbo ènìyàn lò láyé, ti fi ọdún méje pọ̀ si láti ọdún 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà ọdún yìí, yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀, ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè to ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Móríwú

  • Aworan bi omi okun se ru titi de odidi ile kan ni Ayetoro
  • Agolo ohun mimu Energy Drink kan
  • Yara ikawe ti iji ojo lile si lọ
  • Erekusu Ẹ̀bá to wa lẹb omi nla
  • Aworan akọle ileewe naa
  • Aworan
  • Aworan ere Oronna
  • Idamu Industry
  • Aworan Ogboriefon
  • Aworan oni ipele meji ti loko laya n jo ninu ile ni ipele kini l'oke ti obinrin kan si n soro ni ipele ti isale
  • Abayomi Alvin wọ asọ shaati dudu, o de fila bẹnti gọ, o si fi ẹgba ọrun sọrun ati igo soju
  • Sola Sobowale wọ asọ kaba gbagẹrẹ alawọ funfun, o duro siwaju ẹrọ amohunbugbẹmu, awọn eeyan kan to yi ka

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ

  1. 10
    Wo ìbéèrè tí Femi Otedola bi ọmọ rẹ̀, Temi nípa ìgbéyàwó