Ìjà ìlú wa là ń gbè, a gbà, tí ẹ bá ní à ń ṣe ìwà ipá sáwọn àjèjì - Àwọn ọmọ South Africa ṣe ìwọ́de
Ìjà ìlú wa là ń gbè, a gbà, tí ẹ bá ní à ń ṣe ìwà ipá sáwọn àjèjì - Àwọn ọmọ South Africa ṣe ìwọ́de
Fídíò rèé lórí bí àwọn ọmọ ilẹ̀ South Africa ṣe ṣe ìwọ́de láti tako àwọn àjèjì tó wà ní orílẹ̀èdè náà.
Awọn ọmọ ilẹ South Afrika se iwọde pẹlu oniruuru akọle lọwọ wọn lati tako awọn ajeji to wa ni orilẹede wọn.