Tobi Ogunwusi, Olorì Ooni IleIfe sọ̀rọ̀ lórí iṣẹ́ tí a yàn láàyò; àlàyé ọ̀rọ̀ tún jẹyọ lórí bóyá ó dára kí lọ́kọ-láyà ó da owó pọ̀ sí àṣùnwọ̀n kan náà

Àkọlé fídíò, àlàyé ọ̀rọ̀ tún jẹyọ lórí bóyá ó dára kí lọ́kọ-láyà ó da owó pọ̀ sí àṣùnwọ̀n kan náà
Tobi Ogunwusi, Olorì Ooni IleIfe sọ̀rọ̀ lórí iṣẹ́ tí a yàn láàyò; àlàyé ọ̀rọ̀ tún jẹyọ lórí bóyá ó dára kí lọ́kọ-láyà ó da owó pọ̀ sí àṣùnwọ̀n kan náà
Published

Lori eto nibo laye kọjusi ọtẹ yii, Ọkan lara awọn olori Kabiyesi Ọọniriṣa, Adeyẹye Ogunwusi, Ọjaja keji, Jingbini bi atẹ akun, Olori Tobi Ogunwusi ṣalaye pataki fifi ọkan ati ẹmi ṣe iṣẹ ti ẹda ba yan laayo ati riri daju pe irufẹ iṣẹ bẹbẹ jẹ eyi to mu idunnu wa fun wọn.

alapa keji eto nibo laye kọju si ọsẹ yii, ibeere ti a gbe yẹwo naa ni boya o dara ki lọkọlaya o maa pa owo pọ sinu aṣuwọn kan naa?